Song Cover Image

MO SIMI LE JESU -VOL 2

+ Show full styles
V6-MINI

[YORUBA][VERSE 1] Ninu igbi omi okun aiye ti nlu mi Mo faramo Jesu idakoro okan mi Gbat‘idanwo lile fere bori okan mi Mo simi le anu Re, mo gbekele [YORUBA][CHORUS] Mo simi le Jesu ninu igbi aiye Mo simi le Jesu eru koleba mi Mo simi le Jesu enit‘o le gba mi Mo simi le Jesu Apata [YORUBA][VERSE 2] O npa okan mi mo kuro n‘nu gbogbo ibi O np‘ase fun igbi omi nwon ndake roro Olugbala, Amona mi ni y ‘o je titi O mbe nitosi mi lati se ‘ranwo [YORUBA][CHORUS] Mo simi le Jesu ninu igbi aiye Mo simi le Jesu eru koleba mi Mo simi le Jesu enit‘o le gba mi Mo simi le Jesu Apata. [YORUBA][VERSE 3] Mo nsimi le Ore ati Olugbala mi O ndabobo mi O si nle ‘banuje mi lo Igbagbo mi nwoke nibiti ‘ranwo mi wa Mo ri ‘bi isimi t‘o pese fun mi [YORUBA][CHORUS] Mo simi le Jesu ninu igbi aiye Mo simi le Jesu eru koleba mi Mo simi le Jesu enit‘o le gba mi Mo simi le Jesu Apata.